Isé wa bèrè ní odún 2016, láti ran àwon émbásì àti asojú ìjoba ilè Faransé lówó nínú isé àti ìgbìyànjú won nípa ìdáàbobo ètó àwon omo ènìyàn lágbáyé, pàápájùlo àwon émbásì ilè Faransé ní ìlú òkèrè. Àti láti se ìfowósowópò pèlú àwon émbásì ilè òkèrè 60+ nínú ilú Paris. Èròngbàa wa nípàtó dálóri ìdáàbobo ètó àwon omo ènìyàn, àti pàápájùlo láti dáàbòbo ètó àwon àkàndá ènìyàn tí amòsí LGBTI+

Yorùbá